HYMN


E Wole Foba Ologo Julo Lyrics

E wole f'oba, Ologo julo,
E korin ipa ati ife Re;
Alabo wa ni, at' Eni Igbani,
O ngbe 'nu ogo, eleru ni iyin.

E so t' ipa Re, e so t' ore Re;
'Mole l' aso Re gobi Re orun,
B' ara ti nsan ni 'keke, ibinu Re;
Ipa ona Re ni a ko si le mo.

Aiye yi pelu ekun re gbogbo,
Olorun, agbara Re l' o da won;
O fi idi re mu 'le, ko si le yi,
O si f' okun se oja igbaiya re.
Itoju Re wa lara gbogbo won,
Ninu afefe, ninu Imole;
Itoju Re wa nin' odo ti o nsan,
O si wa ninu iri ati ojo.

Awa erupe, aw' alailera,
'Wo l' a gbekele, O ki o da Ni;
Anu Re ronu, o si le de opin
Eleda, Alabo, Olugbala wa.

'Wo alagbara, Onife julo,
B' awon angeli ti nyin O loke,
Be l' awa eda Re, niwon t' a le se
A o ma juba Re, a o ma yin O.

Watch Hymn E Wole Foba Ologo Julo video
Hottest Lyrics with Videos
d10a1e785eec992ad418dee750a96ee2

check amazon for E Wole Foba Ologo Julo mp3 download
these lyrics are last corrected by Afolabi Folarin on January 13, 2020

Official lyrics by

Rate E Wole Foba Ologo Julo by Hymn (current rating: 7.88)
12345678910
Meaning to "E Wole Foba Ologo Julo" song lyrics
captcha
Characters count : / 50
Latest Posts