ANGELIQUE KIDJO

- Ominira Lyrics

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aseyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji
Mmm ewa ka lo

Ka lo fè wa tchitchè kori ominira
N'tori ominira toro ishè gan
Edahoun gbogbo yin foun ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji

Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji

Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo a

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Watch Angelique Kidjo Ominira video

Facts about Ominira

When was Ominira released?


Ominira is first released on April 08, 2002 as part of Angelique Kidjo's album "Black Ivory Soul" which includes 12 tracks in total. This song is the 9th track on this album.

Which genre is Ominira?


Ominira falls under the genre World.
Hottest Lyrics with Videos
4c25cbf9d882310f6ad0abe6398f80d9

check amazon for Ominira mp3 download
these lyrics are submitted by BURKUL4
Record Label(s): 2002 Sony Music Entertainment Inc WARNING All Rights Reserved Unauthorized duplication is a violation of applicable laws
Official lyrics by

Rate Ominira by Angelique Kidjo (current rating: 7.40)
12345678910

Meaning to "Ominira" song lyrics

captcha
Characters count : / 50
Latest Posts